Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì ọba sì wí pé, “Ẹ pe Sadókù àlùfáà wọlé fún mi àti Nátanì wòlíì àti Bẹ́náyà ọmọ Jéhóíádà.” Nígbà tí wọ́n wá ṣíwájú ọba,

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:32 ni o tọ