Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bátíṣébà sì tẹríba, ó sì kúnlẹ̀ níwájú ọba.Ọba sì béèrè pé, “Kí ni ìwọ ń fẹ́?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:16 ni o tọ