Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Bátíṣébà lọ rí ọba ní inú yàrá rẹ̀, ọba sì gbó gidigidi níbi tí Ábíságì ará Súnémù sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún ọba.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:15 ni o tọ