Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣálúmì ọmọ kórè ọmọ Ébíásáfì, ọmọ kórà, àti àwọn olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà ẹlẹ́gbẹ́ Rẹ̀. Láti ìdílé Rẹ̀ (àwọn ará kórà) ni ó dúró fún ṣíṣọ́ ìlóró ẹnu ọ̀nà àgọ́ gẹ́gẹ́ bí baba wọn ti ń dúró fún ṣíṣọ́ à bá wọlé ibùgbé Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:19 ni o tọ