Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ti wà ní ipò ìdúró ní ẹnu ọ̀nà ọba ní apá ìhà ìlà oòrùn títí di àkókò yí. Wọ̀nyí ni àwọn olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà tí ó jẹ́ ti ìpàgọ́ àwọn ará Léfì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:18 ni o tọ