Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 8:26-28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

26. Ṣámíséráì, Ṣéháríà, Átalíà

27. Járéṣíà Élíjà àti Ṣíkírì jẹ́ àwọn ọmọ Jéróhámù.

28. Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ó lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 8