Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 8:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn wọ̀nyí jẹ́ olórí àwọn ìdílé, olóyè gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ó lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ baba ńlá wọn, wọ́n sì ń gbé ní Jérúsálẹ́mù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 8

Wo 1 Kíróníkà 8:28 ni o tọ