Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 6:37-40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

37. Ọmọ Táhátì, ọmọ Áṣírì,ọmọ Ébíásáfì ọmọ Kóráhì,

38. ọmọ Íṣíhárì, ọmọ Kóhátìọmọ Léfì, ọmọ Ísírẹ́lì;

39. Hémánì sì darapọ̀ mọ́ Ásátì, ẹni tí Ó sìn ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ̀:Ásátì ọmọ bérékíáhì, ọmọ Ṣíméà,

40. Ọmọ Míkáélì, ọmọ Bááséíáhì,ọmọ Málíkíjáhì

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6