Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 6:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. Èyí ní àwọn ọkùnrin Dáfídì tí a fi sí ìdí orin nínú ilé Olúwa lẹ́yìn tí àpótí ẹ̀rí ti wá láti sínmìn níbẹ̀.

32. Wọ́n jíṣẹ́ pẹ̀lú orin ńiwájú Àgọ́ ìpàdé títí tí Ṣólómónì fi kọ́ ilé Olúwa ní Jérúsálẹ́mù. Wọ́n se iṣẹ́ ìsìn wọn ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà tí a fi lélẹ̀ fún wọn.

33. Wọ̀nyí ni àwọn ọkùnrin tí ó sìn pẹ̀lú ọmọ wọn:Láti ọ̀dọ̀ àwọn ará Kóhátítè:Hémánì olùkọrin,ọmọ Jóẹ́lì, ọmọ Ṣámúẹ́lì,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6