Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 6:1-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Àwọn ọmọ Léfì:Gérísónì, Kóhátì àti Mérárì.

2. Àwọn ọmọ Kóhátì:Ámírámù, Ísárì, Hébírónì, àti Húsíélì.

3. Àwọn ọmọ Ámírámù:Árónì, Mósè àti Míríámù.Àwọn ọmọkùnrin Árónì:Nádábù, Ábíhù, Élíásérì àti Ítamárì.

4. Élíásérì jẹ́ baba Fínéhásì,Fínéhásì baba Ábísúà

5. Ábísúà baba Búkì,Búkì baba Húṣì,

6. Húsì baba Ṣéráhíà,Ṣéráhíà baba Méráíótì,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 6