Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 5:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí náà Ọlọ́run Ísírẹ́lì ru ẹmi Púlù ọba Ásíríà sókè, ó si kó wọn lọ, àní àwọn ọmọ Rúbẹ́nì àti àwọn ọmọ Gádì, àti ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè, ó sì kó wọn wá sí Hálà, àti Hábórì, àti Hárà, àti sí ọ̀dọ̀ Gósánì; títí dí òní yìí.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 5

Wo 1 Kíróníkà 5:26 ni o tọ