Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 4:41 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin tí a kọ orúkọ Rẹ̀ sókè wà ní ọjọ́ Hésékíà ọba Júdà àti àwọn ibùgbé wọn àti pẹ̀lú àwọn ará Máhúnì ẹni tí ó wà níbẹ̀ tí ó sì pa wọ́n run pátapáta. Gẹ́gẹ́ bí ó ṣe jẹ́ ẹ̀rí títí di òníyìí. Nígbà náà wọ́n sì ń gbé ní iye wọn, nítorí pé koríko wà fún àwọn agbo ẹran wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4

Wo 1 Kíróníkà 4:41 ni o tọ