Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 4:4-8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. Pénúélì sì ni baba Gédórì, àti Édérì baba Húṣà.Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ Húrì, Àkọ́bí Éfúrátà àti baba Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.

5. Áṣárì bàbá Jékóà sì ní aya méjì, Hélà àti Nárà.

6. Nárà sì bí Áhúsámù, Héférì Téménì àti Háhásítarì. Àwọn wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ Nátà.

7. Àwọn ọmọ Hélà:Ṣérétì Ṣóárì, Étanì,

8. Àti kósì ẹnítí ó jẹ́ baba Ánúbì àti Hásóbébà àti ti àwọn Ẹ̀yà Áháríhélì ọmọ Hárúmù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4