Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 4:33-38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

33. Àti gbogbo ìletò tí ó wà ní agbégbé àti gẹ́gẹ́ bí ó ti dé Bálì Àwọn wọ̀nyí ni ibùgbé wọn, wọ́n sì pa ìwé ìtàn ìdílé mọ́.

34. Méṣóbábù Jámilékì, Jóṣáì ọmọ Ámásáyà,

35. Jóẹ́lì, Jéhù ọmọ Jósíbíà, ọmọ Ṣéráíáyà, ọmọ Ásíẹ́lì,

36. Àti pẹ̀lú Élíóénáì, Jákóbà, Jéṣóháiyá, Ásáíyà, Ádíélì, Jésímíẹ́lì, Bénáíyà,

37. Àti Ṣísà ọmọ ṣífì ọmọ Álónì, ọmọ Jédáíyà, ọmọ Ṣímírì ọmọ Ṣémáíyà.

38. Àwọn ọkùnrin tí a dárúkọ lókè yìí àwọn ni ìjòyè ìdílé wọn. Àwọn ìdílé sì pọ̀ síi gidigidi,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4