Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jábésì sì kígbe sókè sí Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí pé, “Áà, Ìwọ yóò bùkún fún, ìwọ yóò sì mú agbégbé mi tóbi! Jẹ́ kí ọwọ́ rẹ kí ó wà pẹ̀lú mi kí o sì pa mí mọ́ kúrò nínú ibi; kí èmi kí ó le ní ìdáǹdè kúrò nínú ìrora.” Ọlọ́run sì gbọ́ ohùn ẹ̀bẹ̀ Rẹ̀

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 4

Wo 1 Kíróníkà 4:10 ni o tọ