Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 29:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ni ọjọ́ kejì, wọ́n rú ẹbọ sí Olúwa, wọ́n sì rú ẹbọ ọrẹ ṣíṣun sí i: ẹgbẹ̀rún kan akọ màlúù, ẹgbẹ̀rin kan àgbò, àti ẹgbẹ̀rin kan akọ ọ̀dọ́ àgùntàn. Lápapọ̀ pẹ̀lú ọrẹ mímu àti àwọn ẹbọ mìíràn ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ fún gbogbo Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:21 ni o tọ