Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 28:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ìwọ̀n ìdá wúrà fún Pẹpẹ tùràrí ó fún un ní ètò fún kẹ̀kẹ́, ìyẹn ni pé àwọn ìdúró kérúbù wúrà tí wọ́n tan iye wọn ká, wọ́n sì bo àpótí ẹ̀rí májẹ̀mú Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:18 ni o tọ