Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 28:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ̀n kìkìdá wúrà fún àwọn àmúga ìjẹun, àwọn ìbùwọ̀n ọpọ́n àti àwọn ìkòkò ìpọnmi; Ìwọ̀n wúrà fún gbogbo àwo pọ̀ọ́kọ̀; fàdákà;

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:17 ni o tọ