Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 27:29-31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

29. Ṣítíráì ará Ṣárónì wà ní idi fífi ọwọ́ ẹran jẹ ko ní Ṣárónì.Ṣáfátì ọmọ Ádíláì wà ní ìdí àwọn ọ̀wọ́-ẹran ní àwọn pẹ̀tẹ́lẹ̀.

30. Óbílì ará Íṣímáélì wà ní ìdí àwọn ìbákasíẹ.Jéhidéísì ará Mérónótì wà ní ìdí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́.

31. Jáṣíṣì ará Hágírì wà ní ìdi àwọn agbo-ẹran.Gbogbo wọ̀nyí ni àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n wà ní ìdí ẹrù ọba Dáfídì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27