Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 27:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíméhì ará Rámátì wà ní ìdí àwọn ọgbà àjàrà.Ṣábídì ará Ṣífímì wà ní ìdí mímú jáde ti èṣo àjàrà fún ọpọ́n ńlá tí a ń fi ọ̀tún èso àjàrà sí.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 27

Wo 1 Kíróníkà 27:27 ni o tọ