Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 26:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pẹ̀lú gbogbo nǹkan tí a yà sọ́tọ̀ láti ọ̀dọ̀ Ṣámúẹ́lì aríranl àti nípasẹ̀ Ṣọ́ọ̀lù ọmọ Kíṣì, Ábínérì ọmọ Nerì àti Joábù ọmọ Ṣeruíà gbogbo ohun tí a yà sọ́tọ̀ sì wà ní abẹ́ ìtọ́jú Ṣélómítì àti àwọn ìbátan Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:28 ni o tọ