Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 26:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣélómítì àti àwọn ìbátan Rẹ̀ jẹ́ alábojútó ilé ìṣúra fún àwọn ohun tí à ti yà sọ́tò nípa ọba Dáfídì, nípaṣẹ̀ àwọn olórí àwọn ìdílé tí wọ́n jẹ́ alákóso ọrọrún àti nipaṣẹ̀ alákóṣo ọmọ-ogun mìíràn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 26

Wo 1 Kíróníkà 26:26 ni o tọ