Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 24:9-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

9. Ẹ̀karùn-ún sì ni Maíkíyà,ẹlẹkẹ́fà sì ni Míjámínì,

10. Ẹ̀kẹ́je sì ni Hakósì,ẹlẹ́kẹ́jọ sí ni Ábíjà,

11. Ẹkẹ́sàn sì ni Jésúà,ẹ̀kẹ́wà sì ni Ṣékáníà,

12. Ẹ̀kọ́kànlá sì ni Élíásíbù,ẹlẹ́kẹjìlá sì ni Jákímù,

13. Ẹ̀kẹtàlá sì ni Húpà,ẹlẹ́kẹrìnlá sì ni Jéṣébéábù,

14. Ẹkẹdógun sì ni Bílígà,ẹ̀kẹ́rìndílogún sì ni Ímerì

15. Ẹ̀kẹtàdílógún sì ni Héṣírì,ekejìdílógún sì ni Háfísesì,

16. Ẹ̀kọkàndílógún sì ni Pétalà,ogún sì ni Jéhésékélì,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 24