Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 24:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A rí ọ̀pọ̀ àwọn olórí lára àwọn ọmọ Élíásérì ju lára àwọn ọmọ Ítamárì lọ, wọ́n sì pín wọn lẹ́sẹ lẹ́sẹ: mẹ́rindínlógún (16) olórí láti ìdílé ọmọ Élíásérì ìran wọn àti olórí méjọ ìdílé láti ara àwọn ọmọ Ítamárì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 24

Wo 1 Kíróníkà 24:4 ni o tọ