Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 24:15-18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

15. Ẹ̀kẹtàdílógún sì ni Héṣírì,ekejìdílógún sì ni Háfísesì,

16. Ẹ̀kọkàndílógún sì ni Pétalà,ogún sì ni Jéhésékélì,

17. Ẹ̀kọ́kànlélógún sì ni Jákínì,ẹ̀kẹ́rìnlélogún sì ni Gámúlì,

18. Ẹ̀kẹtàlélógún sì ni Déláyà,ẹ̀kẹrìnlélógún sì ni Másíà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 24