Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 23:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní gbàkúgbà ẹbọ ọrẹ sísun ni wọ́n fi fún Olúwa ní ọjọ́ ìsinmi àti ní àsìkò oṣù tuntun àti ní ọjọ́ wọ̀n-ọn-nì tí a paláṣẹ. Wọ́n gbọdọ̀ sìn níwájú Olúwa lójojúmọ́ ní iye tó yẹ àti ní ọ̀nà tí a ti paláṣẹ fún wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 23

Wo 1 Kíróníkà 23:31 ni o tọ