Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 23:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì gbọdọ̀ dúró ní gbogbo òwúrọ̀ láti dúpẹ́ àti láti yin Olúwa. Wọ́n sì gbọdọ̀ ṣe irú kan náà ní àsálẹ́.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 23

Wo 1 Kíróníkà 23:30 ni o tọ