Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì paláṣẹ láti kó àwọn àlejò tí ń gbé ní Ísírẹ́lì jọ, àti wí pé lára wọn ni ó ti yan àwọn agbé-òkúta láti gbé òkúta dáradára láti fi kọ́lé Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 22

Wo 1 Kíróníkà 22:2 ni o tọ