Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 22:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Èmi ti gba Ìpọ́nju ńlá láti ṣe fún ile Olúwa ọ̀kẹ́ márùn ún talẹ́ńtì wúrà, àti ẹgbẹ̀rún ẹgbẹ̀rún talẹ́ntì fàdákà, Ìwọ̀n idẹ àti irin tí ó tóbi àìní ìwọ̀n, àti ìtì igi àti òkúta. Ìwọ sì tún le fi kún wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 22

Wo 1 Kíróníkà 22:14 ni o tọ