Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 21:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọdún mẹ́ta ìyàn, oṣù mẹ́ta gbígbá lọ niwájú àwọn ọ̀tá rẹ, pẹ̀lú idà wọn láti lé ọ bá, tàbí ọjọ́ mẹ́fà idà Olúwa ọjọ́ àjàkálẹ̀-àrùn ní ilẹ̀ náà, pẹ̀lú àwọn ángẹ́lì Olúwa láti pa gbogbo agbègbè Ísírẹ́lì run.’ Nísinsi yìí ǹjẹ́, ronú bí èmi yóò ti ṣe dá ẹni tí ó rán mi lóhùn.”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 21

Wo 1 Kíróníkà 21:12 ni o tọ