Dáfídì mú adé kúrò lórí àwọn ọba wọn ìwọ̀n Rẹ̀ dàbí i talẹ́ńtì wúrà, a sì tò ó jọ pẹ̀lú àwọn òkúta iyebíye. A sì gbé e ka orí Dáfídì. Ó kó ọ̀pọ̀ ìkógun láti ìlú ńlá náà.