Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 20:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò àkọ́rọ̀ òjò, ni ìgbà tí àwọn ọba lọ sí ogun, Jóábù ṣamọ̀nà àwọn ọ̀wọ́ ọmọ ogun. Ó fi ilẹ̀ àwọn ará Ámónì ṣòfò. Ó lọ sí ọ̀dọ̀ Rábà. Ó sì fi ogun dúró tì í. Ṣùgbọ́n Dáfídì dúró sí Jérúsálẹ́mù Jóábù kọlu Rábà, ó sì fi sílẹ̀ ní ìparun.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 20

Wo 1 Kíróníkà 20:1 ni o tọ