Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 2:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣésánì kò sì ní ọmọkùnrin àwọn ọmọbìnrin nìkan ni ó ní.Ó sì ní ìránṣẹ́ ará Éjíbítì tí orúkọ Rẹ̀ ń jẹ́ Járíhà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 2

Wo 1 Kíróníkà 2:34 ni o tọ