Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 19:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí a sọ fún Dáfídì nípa èyí, ó pe gbogbo Ísírẹ́lì jọ wọ́n sì rékọjá Jódánì; Ó lọ ṣíwájú wọn, ó sì fa ìlà ogun dojúkọ wọ́n. Dáfídì fa ìlà Rẹ̀ láti bá àwọn ará Ṣíríà jagun wọ́n sì doju ìjà kọ ọ́.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 19

Wo 1 Kíróníkà 19:17 ni o tọ