Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìgbà tí àwọn ará Ṣíríà rí wí pé àwọn Ísírẹ́lì ti lé wọn, wọ́n rán ìránṣẹ́. A sì mú àwọn ará Ṣíríà rékọjá odò wá, pẹ̀lú Ṣófákì alákóso ọmọ ogun Hádádésérì, tí ó ń darí wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 19

Wo 1 Kíróníkà 19:16 ni o tọ