Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 19:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ alágbára kí ẹ sì jẹ́ kí a jà pẹ̀lú ìgboyà fún àwọn ènìyàn wa àti àwọn ìlú ńlá ti Ọlọ́run wa. Olúwa yóò ṣe ohun tí ó dára ní ojú Rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 19

Wo 1 Kíróníkà 19:13 ni o tọ