Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 18:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò kan, Dáfídì kọlu àwọn ará Fílístínì, ó sì sẹ́gun wọn. Ó sì mú Gátì àti àwọn ìlétò agbègbè Rẹ̀ kúrò lábẹ́ ìdarí àwọn ará Fílístínì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 18

Wo 1 Kíróníkà 18:1 ni o tọ