Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 17:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ni ibi gbogbo tí mo ti bá gbogbo Isírẹ́lì rìn dé, ǹjẹ́ mo wí nǹkankan sí ọ̀kan nínú àwọn adarí Ísírẹ́lì, tí èmí pàṣẹ́ fún láti máa jẹ́ olùṣọ́-àgùntàn àwọn ènìyàn mi, wí pé, “Kí ní ṣe tí ẹ̀yín kò fi kọ́ ilé tí a fi igi kédárì kọ́ fún mi?” ’

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 17

Wo 1 Kíróníkà 17:6 ni o tọ