Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 17:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí ó ti tẹ́ ọ lọ́rùn láti bùkún ilé ìransẹ́ rẹ kí ó lè tẹ̀ṣíwájú ní ojú rẹ; nitorí ìwọ, Olúwa, ti bùkún un, a ó sì bùkun-un títí láéláé.”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 17

Wo 1 Kíróníkà 17:27 ni o tọ