Olùbùkún ni Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì,láé àti láéláé.Lẹ́yìn náà gbogbo àwọn ènìyàn wí pé “Àmín” wọ́n sì Yin Olúwa.