Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 16:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sunkún jáde, “Gbà wá, Ọlọ́run Olùgbàlà a wa;kówajọ kí o sì gbà wá kúrò lọ́wọ́ àwọn orílẹ̀ èdè,kí àwa kí ó lè fí ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ,kí àwa kí ó lè yọ̀ nínú ìyìn Rẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 16

Wo 1 Kíróníkà 16:35 ni o tọ