Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 14:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Dáfídì sì tún bèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run, Ọlọ́run sì dalóhùn pé, Má se gòké tàrà, ṣùgbọ́n ẹ yí wọn ká kí ẹ sì mú wọn níwájú igi Múlíbérì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 14

Wo 1 Kíróníkà 14:14 ni o tọ