Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Díẹ̀ lára àwọn ará Gádì yà sọ́dọ̀ Dáfídì ní ibi gíga ní ihà. Wọ́n sì jẹ́ onígboyà ológun tí ó múra fún ogun tí ó sì lágbára láti di àṣà àti ẹsin mú. Ojú wọn sì dàbí ojú kìnìún, wọ́n sì yára bí àgbọ̀nrín lórí àwọn òkè.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 12

Wo 1 Kíróníkà 12:8 ni o tọ