Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 12:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ọkùnrin Ísákárì, àwọn ẹni tí ó mọ ìgbà yẹn ó sì mọ ohun tí Ísírẹ́lì yóò se ìgbà (200) àwọn ìjòyè, pẹ̀lú gbogbo àwọn ìbátan wọn lábẹ́ òfin wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 12

Wo 1 Kíróníkà 12:32 ni o tọ