Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

èyí sì ni iye àwọn alágbára ọkùnrin Dáfídì:Jásóbéámù ọmọ Hákúmónì, òun sì ni olórí nínú àwọn ìjòyè, ó sì gbé ọ̀kọ̀ Rẹ̀ sókè lórí àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ènìyàn, àwọn ẹni tí ó pa ní ogun ẹ̀ẹ̀kan.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:11 ni o tọ