Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn wọ̀nyí sì ni ìjòyè alágbára ọkùnrin Dáfídì, àwọn pẹ̀lú gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, wọ́n sì fún ìjọba Rẹ̀ ní àtìlẹ́yìn tó lágbára láti mú un tàn káàkiri gbogbo ilẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti sèlérí:

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 11

Wo 1 Kíróníkà 11:10 ni o tọ