Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 10:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n gbé ìhámọ́ra Rẹ̀ sí inú ilé tí wọ́n kọ́ fún òrìsà wọn, wọ́n sì fi orí Rẹ̀ kọ́ sí inú ilé Dágónì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 10

Wo 1 Kíróníkà 10:10 ni o tọ