Gbọ́ igbe mi;nítorí wọ́n ti rẹ̀ mí sílẹ̀ patapata.Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi,nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.