Ó ń yan kiri láàrin àwọn kinniun;nítorí ó ti di ọ̀dọ́ kinniun tí ó lágbára,ó kọ́ bí wọn tí ń ṣe ọdẹ,ó sì ń pa eniyan jẹ.