Nígbà tí abo kinniun náà rí i pé ọwọ́ tẹ ọmọ òun,ati pé igbẹkẹle òun ti dòfo,ó mú òmíràn ninu àwọn ọmọ rẹ̀,ó tọ́ ọ di ọ̀dọ́ kinniun.